Munbari Agbaye icon

Munbari Agbaye

★★★★★
★★★★★
(0.00/5)

1.0Free10 years ago

Download Munbari Agbaye APK latest version Free for Android

Version 1.0
Update
Size 5.2M
Developer kamal said fahmy
Category Apps, Entertainment
Package Name com.minberLib.minberYo
OS 2.1 and up

Munbari Agbaye APPLICATION description

Eto Munbari Agbaye ngbero lati se imudogongo ati lati fon awon agboye esin Islam ti o je ti ipile kaakiri ni ede Yoruba, eleyii yio maa waye lati ara fifon awon agbonrin tabi akole ti o ni onka kaakiri eleyii ti a o maa gbe jade lati ara gbogbo ilana ti o wa gegebi ero ayarabiasa(computer) ati ero alatagbangba(internet) eyiti yio maa ko fidio/ egbaoro/ohun/aworan sinu, gegebi a o tun se maa fon kaakiri ni aworan iwe eko, ni afikun, a o tun maa gbe si ori ero ti o wa fun nkan ihaha(iphone-ipod-ipad).
Eto Munbari Agbaye ti a ba wo awon agbonrin tabi akole re, a o ri wipe o da lori awon abala eleyii ti o se pataki ti o ni onka gegebii:
www.yorubaminbar.com
1. Abala ti igbagbo: ninu awon akole ti o wa ni abala yi ni; (Attaoheed(Ise Olohun Oba Alekeola lokan),ati alaye awon oruko Olohun ti o rewa, igb’arale Olohun,ogba idera(Alujannah) ati ina, awon aamin ojo igbende alukiyama ati awon ti o yato si eleyii ninu awon akole).
2. Abala ti ibasepo lawujo: ninu awon akole ti o wa ni abala yi ni; isedaadaa si obi mejeeji, aponle ti o wa fun obinrin ninu esin Islam, zakah yiyo, ilana ibesepo pelu eniti kii se musulumi, ati bee bee lo.
3. Abala ifunni niro: ninu awon akole tabi agbonrin ti o wa ni abala yi ni; awon ilana ti a le gba jere okan, isenilojukokoro wiwa mimo ati lilo re, ati bee bee lo.
4. Abala ti iwa: ninu awon akole ti o wa ni abala yi ni; ilenisa nibi asise ahon, ironupiwada kuro nibi awon ese, ewu ti o wa nibi ijade ti ko dara fun obinrin musulumi, awon oripa awon nkan oloro lori awon odo, iba’ra enilopo eleyi ti ko ba ofin mun, ati bee bee lo.
5. Abala ti ijosin: ninu awon akole ti o wa ni abala yi ni; bi a ti le paya Olohun oba lori irun, ikona osu Ramadan, ola ti o wa fun awon ojo mewa akoko osu Dhul-hijjah, ilenisa kuro nibi adadaale, ati bee bee lo.
6. Abala ti poposinsin: ninu awon akole ti o wa ni abala yi ni; odun ileya, irun ti a fi nwa riro ojo, irun ti oorun tabi osupa ba teri, ati bee bee lo.
Awon akole wonyii yio maa di eleyi ti a o gbe sinu awon tiira, bakannaa, a o gbe jade lori ero muhunmaworan ati ero asoromagbesi, a o tun gbe jade lori ero alatagbangba(internet) ati awon ilana ifunni niro tuntun, a o si tun se awon awo siidi(cd) eleyii ti o ko awon akole wonyii sinu boya eleyii ti a te nibe ni tabi eleyi ti o je onimuhunmaworan tabi oni ohun, gegebii a tun se maa gbe awon akole wonyii jade lori awon saneeli(channels) ati awon ilese reedio oniranran eleyii ti o nso ede Yoruba.
Eto Munbari Agbaye ngbero Läti's imudogongo ati Läti fon AWON agboye ESIN Islam ti o je ti ipile kaakiri ni oaths Yoruba, eleyii yio Mar waye Läti ara FIFON AWON agbonrin Tabi akole ti o ni onka kaakiri eleyii ti ao Mar FBE jade Läti ara gbogbo Ilana ti o wa gegebi ero ayarabiasa (computer) ati ero alatagbangba (internet) eyiti yio maa ko fidio / egbaoro / ohun / aworan sinu, gegebi ao tun's Mar fon kaakiri ni aworan iwe eco, ni afikun Warrant Officer tun Mar FBE si ori ero ti o wa fun nkan ihaha (iphone-ipod-ipad).
Eto Munbari Agbaye ti a ba wo AWON agbonrin Tabi akole re Warrant Officer ri wipe o da lorikeet AWON abala eleyii t o t o s Pataki ni onka gegebii:
www.yorubaminbar.com
1. Abala ti igbagbo: ninu AWON akole ti o wa ni ni yi abala; (Attaoheed (Ise Olohun Oba Alekeola lokan) ati alaye AWON oruko Olohun ti o Rewa, igb'arale Olohun, ogba Idera (Alujannah) ati ina, AWON Aamin ojo igbende alukiyama ati AWON ti o si yato eleyii ninu AWON akole).
2. Abala ti ibasepo lawujo: ninu AWON akole ti o wa ni ni yi abala; isedaadaa si obi mejeeji, aponle ti o wa fun obinrin ninu ESIN Islam, zakah yiyo, Ilana ibesepo pelu eniti kii's musulumi, ati bee bee lo.
3. Abala ifunni Niro: ninu AWON akole Tabi agbonrin ti o wa ni ni yi abala; AWON Ilana ti a le gba Jere Okan, isenilojukokoro Wiwa mimo ati re Lilo, ati bee bee lo.
4. Abala ti iwa: ninu AWON akole ti o wa ni ni yi abala; ilenisa NIBI axles ahon, ironupiwada Kuro NIBI AWON ese, EWU ti o wa NIBI ijade ti ko dara fun obinrin musulumi, AWON oripa AWON nkan oloro lorikeet AWON Odo, iba'ra enilopo eleyi ti ko ba ofin mun, ati bee bee lo.
5. Abala ti ijosin: ninu AWON akole ti o wa ni ni yi abala; bi a ti le Paya Olohun oba lorikeet Irun, ikona OSU Ramadan, ola ti o wa fun AWON ojo mewa akoko OSU Dhul Hijjah-, ilenisa Kuro NIBI adadaale, ati bee bee lo.
6. Abala ti poposinsin: ninu AWON akole ti o wa ni ni yi abala; odun ileya, Irun ti a fi NWA riro ojo, Irun ti oorun Tabi osupa ba teri, ati bee bee lo.
AWON akole wonyii yio maa di eleyi ti ao FBE sinu AWON tiira, bakannaa Warrant Officer FBE jade lorikeet ero muhunmaworan ati ero asoromagbesi Warrant Officer tun FBE jade lorikeet ero alatagbangba (internet) ati AWON Ilana ifunni Niro tuntun, ao si tun's AWON awo siidi (CD) eleyii ti o co AWON akole wonyii sinu boya eleyii ti a NIBE to Tabi ni ti o eleyi you onimuhunmaworan Tabi oni ohun, gegebii a tun's Mar FBE AWON akole wonyii jade lorikeet AWON saneeli (channels) ati AWON ilese reedio oniranran eleyii ti o NSO oaths Yoruba.
↓ Read more
Munbari Agbaye screen 1 Munbari Agbaye screen 2 Munbari Agbaye screen 3 Munbari Agbaye screen 4 Munbari Agbaye screen 5 Munbari Agbaye screen 6 Munbari Agbaye screen 7